F-ELECTRICITE.FR ≡ Confectionery Chairs, Beds, Tents, Umbrellas Shoulder Bags Books
  • Yoruba Books

  • Awon Oju Odu Meerindinlogun

Awon Oju Odu Meerindinlogun

$38.14 $48.06
DescriptionIwẻ yií je àkójopò ese Ifá ti a mú láti inú àwon Ojú Odù (Olojà) Mérèerindinlógún. A mú ese Ifá méjo-méjo láti inů Odù kookan bèrè láti inú Eji Ogbè títi tí ó fi kan Ofün (Oràngún) Méji. lyàtò ti ở wà nínú iwé yii àti àwon iwé Ifá ati ewi àdáyébá miiràn ni pé a se àlàyé ese Ifå kòòkan tiń bẹ ninú iwé yii léseese. A se èyí nitori pé ati şe àkiyèsi wi pé àwon ese Ifá wonyí kii yé àwon akékoo àti olùkó náà dáadáa nigbà tí won bá ń kà won. Edè àtayé báyé ni èdè Orúnmilà. Nitorí náa kò ya ‘ni lénu wipé èdè lIfá ki í tètè yé ogbèri. ldi niyí ti a fi se àlàyé sókisókí lóri esę koökan. Fún eni ti ó bá ni òye ti ó si ní ife si ese Ifä, a lérò pé àlàyé wònyi ó jèe ilànà pàtäki nigbà ti ó bań ka iwé yii finífini. Ni ibère iwé yii, a se àlàyé nipa ohun ti Ifa je gége bi orisà àti ewi àdáyébá Yorùbá. A lérò wi pé àlàyé yii náà ó ran àwỌn ònkàwé wa lówó láti mo ipò ti Ifá kó ninú ogbộn, imò àti iríri omo Yorùbá.
Yoruba Books

Yoruba Books

  • 230 Yoruba Proverbs And Their Translation Into English And French With Their Meaning
    $52.85 $100.41
  • In The Forest Of Eledumare
    $44 $87.56
  • A Dictionary Of The Yoruba Language
    $37.57 $64.61
  • Asa Ati Ise Yoruba
    $73.43 $88.12
  • The Mysteries of God, A translation of D. O. Fagunwa’s Adiitu Olodumare
    $75.39 $141.74
  • Ijapa Tiroko: Oko Yannibo
    $41.27 $70.15
  • Ijinle Ohun Enu Ifa (Apa Kin-in-ni)
    $38.87 $65.69
  • 256 Divine Invocation: The Spiritual Power of the Yorubas
    $80.6 $152.34
  • Aja Lo Leru
    $80.82 $125.27
  • Ijinle Ohun Enu Ifa (Apa Keji)
    $36.63 $47.62
  • Ireke Onibudo, An English Translation of D. O. Fagunwa’s Ireke Onibudo
    $35.36 $65.77
  • The Novel of D.O Fagunwa – A commentary
    $50.76 $76.14
  • Iwe Mimo Ifa: Esin Akoda Olodumare
    $72.37 $117.24
  • O Le Ku
    $70.78 $112.53
  • The Forest of a Thousand Daemons
    $60.29 $91.64
  • Ka Rin Ka Po (Apa Keta Aja Lo Leru)
    $65.21 $111.52

© 2026 - F-ELECTRICITE.FR