F-ELECTRICITE.FR ≡ Confectionery Chairs, Beds, Tents, Umbrellas Shoulder Bags Books
  • Yoruba Books

  • O Le Ku

O Le Ku

$70.78 $112.53
DescriptionIwe yii fi ojúlówó Yorúba so nipa awon isoro ti odomokùnrin ti ở i wá aya máa i bá pàdé. Ajani sest jáde ni yunifásiti ni. O fé te Asáke odomobinrin téere awclewa kan ti oun nà sese pari iwè mnéwàá. Asaké fi gbogbo ara wu Ajàni, sugbón àimowé púpò Asàké ko Ajani lóminú. Lols, omobinrin miiràn fe ba ààrin won jé. Sügbón, babá Asake kékeré kò fệ ki Asàké fé Ajáni. Oyún ti Aşaké ni l’ó pari orò. Sugbộn Aşàké kò fi oyún náà bi omo. Aarin won tún darú. Nigbèhin, ayò Ajàni kún lójó t’ó wá fé Sadé, eni ti kò kàwé tó bée, sugbón ti ó ti ilé rere wá. Ayò náa ko kún dalé nítori pé Ajaní kú ikú mộtò nigbà ti ó n lọ rèé wo Asàké ti ó fé binú kú ni ilé-iwòsan. Iwé yif dára púpò gégé bii litiréso fün àwon t’ó fe se idánwò bájáde ni ilé-iwé giga àti àwon olukóni, àti fún awon akekoó giga àti t’àwon olukóni, àti awon akékoó Yorübá ni ilé-¢kó giga yunifásiti pèlú; yió si tún jé iwé aládun fún gbogbo àwon tí ó nifeé Yorùbá ni kika. Iyán rèé, obè niyi, iyókù kù sówò eni ebi ń pa?
Yoruba Books

Yoruba Books

  • Ijinle Ohun Enu Ifa (Apa Kin-in-ni)
    $38.87 $65.69
  • The Novel of D.O Fagunwa – A commentary
    $50.76 $76.14
  • A Dictionary Of The Yoruba Language
    $37.57 $64.61
  • Ireke Onibudo, An English Translation of D. O. Fagunwa’s Ireke Onibudo
    $35.36 $65.77
  • Iwe Mimo Ifa: Esin Akoda Olodumare
    $72.37 $117.24
  • The Mysteries of God, A translation of D. O. Fagunwa’s Adiitu Olodumare
    $75.39 $141.74
  • Aja Lo Leru
    $80.82 $125.27
  • In The Forest Of Eledumare
    $44 $87.56
  • Asa Ati Ise Yoruba
    $73.43 $88.12
  • 230 Yoruba Proverbs And Their Translation Into English And French With Their Meaning
    $52.85 $100.41
  • Ijapa Tiroko: Oko Yannibo
    $41.27 $70.15
  • The Forest of a Thousand Daemons
    $60.29 $91.64
  • Ijinle Ohun Enu Ifa (Apa Keji)
    $36.63 $47.62
  • 256 Divine Invocation: The Spiritual Power of the Yorubas
    $80.6 $152.34
  • O Le Ku
    $70.78 $112.53
  • Ka Rin Ka Po (Apa Keta Aja Lo Leru)
    $65.21 $111.52

© 2026 - F-ELECTRICITE.FR