F-ELECTRICITE.FR ≡ Confectionery Chairs, Beds, Tents, Umbrellas Shoulder Bags Books
  • Yoruba Books

  • Asa Ati Ise Yoruba

Asa Ati Ise Yoruba

$73.43 $88.12
Descriptionlwé Aşi àti lşe Yorùbá jé àbiyori iwádit ijinlę àti italèmú ogün awon babanlá wa ti ó tii sorù bí àwọn àgbàlagbà ti á tán ní abérun ayć. lsé ribirbi ni èyi nitori pé àşà abinibi tí a şe iwádif wònyí j¢ àwon ohun ti a le pè ni àwon igi ti àwọn babańilá wa ti lộ, cjúlówó omọ kò si gbọdò tu ủ, àfi kió bomi rin in. Gbogbo ohun pàtaki ti ak¢kòó àti Olikóni nínú kộ Yorübá gbódộ mộ fün idánwò àşekágbá ilé kộ Sékóńii àgbà (SSCE) nipa àwon yà ti àn pè ni Yorùbá ni a kójo sínů iwẻ yii, Bákan náà ni iwé yìí jệ máyàmí fún akệkòó ilể kộ Olikóni àgbà (NCE) àti akekộo ilé eko Yunifäisiti ti ó yan ekó Yorùba láàyò, ki á tó wả sọ ti ogunlógò àwọn olůfệ aşà àti lşese Yorubá tiyóð fệ mọ àmộdájú nipa irandiran wọn. Aşe ijinlè ảti ekúnrer¢ alàyé lóri itàn orirun, iwà, işe-owó, işe-onà, áşà ati işèşe dwọn tí à ń pề ni omọ Oòduà. Ojúlówó èdè Yorùbá tí ó bá ilàn. ikotó ode-òní mu ni a fi şe agbékalė àwọn iwádi ộrínkinniwin wònyí. Akóký irů rệ rèé, bộệ “ệyin ni qmọ adię ń tòyá e’ni àwon irúfệ iwe yi ti ó wà lóde siá şe fün un títí di òní. Kí á má purý, atá tó o, iyỳ dùn ún ni or) iwé yil. ldi niyí ti Kábiyèsi, Timi ti hú Edę àná, Qba Adétóyèşe Láoyė, fi pe ‘Láògún ni Dókità Yorùbá’, bí ó tilệ jé pé ‘Dökítà Işègùn’ ni Láogún í e. Kò si eni ti yoò ka iwé yií tí kò ní gbà pé ‘Aràbà ni bàbá, ni a bá lábà ni baba’Qgbộn lẹ fệ kộ ni, abi im) ijinlè? O yá ę fàkàrà túko wò.
Yoruba Books

Yoruba Books

  • Ijinle Ohun Enu Ifa (Apa Kin-in-ni)
    $38.87 $65.69
  • A Dictionary Of The Yoruba Language
    $37.57 $64.61
  • Ireke Onibudo, An English Translation of D. O. Fagunwa’s Ireke Onibudo
    $35.36 $65.77
  • In The Forest Of Eledumare
    $44 $87.56
  • Aja Lo Leru
    $80.82 $125.27
  • The Novel of D.O Fagunwa – A commentary
    $50.76 $76.14
  • The Forest of a Thousand Daemons
    $60.29 $91.64
  • Ijinle Ohun Enu Ifa (Apa Keji)
    $36.63 $47.62
  • O Le Ku
    $70.78 $112.53
  • Ijapa Tiroko: Oko Yannibo
    $41.27 $70.15
  • Iwe Mimo Ifa: Esin Akoda Olodumare
    $72.37 $117.24
  • Ka Rin Ka Po (Apa Keta Aja Lo Leru)
    $65.21 $111.52
  • 230 Yoruba Proverbs And Their Translation Into English And French With Their Meaning
    $52.85 $100.41
  • The Mysteries of God, A translation of D. O. Fagunwa’s Adiitu Olodumare
    $75.39 $141.74
  • 256 Divine Invocation: The Spiritual Power of the Yorubas
    $80.6 $152.34
  • Asa Ati Ise Yoruba
    $73.43 $88.12

© 2026 - F-ELECTRICITE.FR